Search

LIVRES NUMÉRIQUES ET LIVRES AUDIO GRATUITS

L’évangile de l’eau et de l’Esprit

Yorouba  1

ǸJẸ́ NÍTÒÓTỌ́ ÌWỌ DI ÀTÚNBÍ NÍ TI OMI ATI TI Ẹ̀MÍ BÍ? [Ìtẹ̀jáde Túnṣe Tuntun]

Rev. Paul C. Jong | ISBN 9788928261871 | Pages 342

Téléchargez des livres numériques et livres audio GRATUITS

Choisissez votre format de fichier préféré et téléchargez-le en toute sécurité sur votre appareil mobile, PC ou tablette pour lire et écouter les collections de sermons n'importe quand et n'importe où. Tous les livres numériques et livres audio sont entièrement gratuits.

Vous pouvez écouter le livre audio via le lecteur ci-dessous. 🔻
Possédez un livre broché
ÀKÓJỌPỌ̀
 
Apá kìíní—Ìwàásù
1. A Gbọ́dọ̀ Kọ́kọ́ Mọ̀ nípa Ẹ̀ṣẹ̀ Wa ná lati lè ní Ìràpadà (Marku 7:8-9, 20-23) — 19
2. A Bí Ènìyàn Ní Ẹlẹ́ṣẹ̀ (Marku 7:20-23) — 35
3. Bí A Bá Ṣe Ohun Gbogbo nípa Òfin, Ó lè Gbàwálà bí? (Luku 10:25-30) — 47
4. Ìràpadà Aiyéraiyé (Johannu 8:1-12) — 69
5. Ìrìbọmi Jesu ati Ètùtù fún Ẹ̀ṣẹ̀ (Matteu 3:13-17) — 99
6. Jesu Kristi Wá nípasẹ̀ Omi, Ẹ̀jẹ̀, ati Ẹ̀mí (1 Johannu 5:1-12) — 145
7. Ìrìbọmi Jesu Ni Àpẹẹrẹ Ìgbàlà Fún Gbogbo Ẹlẹ́ṣẹ̀ (1 Peteru 3:20-22) — 179
8. Ìhìnrere ti Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ètùtù (Johannu 13:1-17) — 197
 
Apá Kejì—Àfikún
1. Ẹ̀rí Ìgbàlà — 259
2. Àfikún Àlàyé — 279
3. Ìbéèrè ati Ìdáhùn — 311
 
 
Àkọ́lé ẹ̀kọ́ yìí gan an ni “lati di àtúnbí níti omi ati ti Ẹ̀mí.” Ó ní ìpìlẹ̀ lórí ẹ̀kọ́ yìí. Ní èdè mìíràn, ìwé yìí fi nyé wa gedegbe ohun tí àtúnbí jẹ́ ati bí a ti lè di àtúnbí níti omi ati ti Ẹ̀mí ní ìbámu pẹlu Bibeli. Omi túmọ̀sí ìrìbọmi nínú odò Jọrdani Bibeli sì wipe gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wa pátá ni ó ti rékọjá sórí Jesu nigbati Ó ṣe ìrìbọmi ní ọ̀dọ̀ Johannu Onítẹ̀bọmi. Johannu ni aṣojú gbogbo ẹ̀dá alààyè tí Ó sì tún jẹ̀ àrọ́mọdọ́mọ Aaroni Olórí alufa. Aaroni gbé ọwọ́ rẹ̀ méjèèjì lé orí ewúrẹ́ alààyè náà ó sì kó gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ Israẹli ti ọdọdún sórí rẹ̀ ní ọjọ́ ètùtù. Èyí jẹ́ òjìjí ohun rere tí mbọ̀ wá. Ìrìbọmi Jesu ni àpẹẹrẹ ètò ìgbọ́wọ́lé. Jesu ṣe ìrìbọmi ní ìlànà ètò ìgbọ́wọ́lé lórí nínú odò Jọrdani. Nitoridi èyí Ó kó gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ aiyé yìí lọ nípasẹ̀ ìrìbọmi Rẹ̀. Ó sì kú lórí àgbélèbú lati san gbèsè ẹ̀ṣẹ̀. Ṣugbọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ Kristiẹni ni kò mọ ìdí tí
Jesu fi ṣe ìrìbọmi ní ọ̀dọ̀ Johannu Onítẹ̀bọmi nínú odò Jọrdani. Ìrìbọmi Jesu ni kókó ọ̀rọ̀ ìwé yìí, ati apákan tí ó jẹ́ dandan sí ìhìnrere ti omi ati ti Ẹ̀mí. A lè di àtúnbí bí a bá nígbàgbọ́ sí ìrìbọmi ti Jesu ati ti ikú Rẹ̀ lórí igi àgbélèbú.
Plus
Livre imprimé gratuity
Ajouter des livres au Panier.

Livres liés à ce titre

The New Life Mission

Participez à notre enquête

Comment avez-vous entendu parler de nous ?